Sáàmù 8:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, Olúwa wa,orúkọ Rẹ̀ ti tó tóbi tó ní gbogbo àyé!Ìwọ ti gbé ògo Rẹ̀ gaju àwọn ọ̀run lọ.

2. Láti ẹnu ọmọ ọwọ́ àti ọmọ ọmúni o ti yan ìyìnnítorí àwọn ọ̀ta Rẹ,láti pa àwọn ọ̀ta àti àwọn olùgbẹ̀san lẹ́nu mọ́.

Sáàmù 8