Sáàmù 77:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú ọwọ́ agbára Rẹ ni ìwọ ra àwọn ènìyàn padà,àwọn ọmọ Jákọ́bù àti Jósẹ́fù. Sela

Sáàmù 77

Sáàmù 77:11-18