Sáàmù 76:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Lóòtọ́, ìbínú Rẹ̀ sí àwọn ènìyàn ń mú ìyìn wá fún ọ,ẹni tí ó yọ nínú ìbínú Rẹ ní a dá nígbà tí ìwọ bá fi ìbínú ìyókù di ara Rẹ ni àmùrè.

11. Jẹ́ ẹ̀jẹ́ sí Olúwa Ọlọ́run Rẹ kí o sì mú-un ṣẹ;kí gbogbo àwọn tí ó yíi kámú ẹ̀bùn wá fún ẹni tí o tọ́ láti bẹ̀rù.

12. Ó ké ẹ̀mí àwọn aládé kúrò;àwọn ọba ayé sì n bẹ̀rù Rẹ̀.

Sáàmù 76