Sáàmù 71:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Nítorí ìwọ jẹ́ ìrètí mi, Olúwa Ọlọ́run,ìwọ ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí láti ìgbà èwe

6. Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi;Ìwọ mu mi jáde láti inú ìyá mi wáèmi ó máa yìn ọ títí láé

7. Mo di ẹni ìyanu fún ọ̀pọ̀ ènìyàn,ṣùgbọ́n ìwọ ni ààbò mi tí ó lágbára.

Sáàmù 71