Sáàmù 69:32-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

32. Àwọn òtòsì yóò rí wọn yóò sì yọ̀:Ẹ̀yin yóò wá Ọlọ́run, ọkàn yin yóò sì wà láàyè!

33. Olúwa, gbọ́ ti aláìníkí o sì kọ àwọn ìgbèkùn sílẹ̀.

34. Kí ọ̀run àti ayé yìn ín,òkun àti àwọn tí ń gbé inú Rẹ̀,

35. Nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Síónì làyóò sì tún àwọn ìlú Júdà wọ̀nyí kọ́.Kí wọn ó lè máa gbé ibẹ̀,kí wọn ó lè máa níi ni ilẹ̀ ìní

36. Àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún Rẹ̀,àwọn ti ó fẹ́ orúkọ Rẹ ní yóò máa gbé inú Rẹ̀.

Sáàmù 69