Sáàmù 69:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ń rì nínú ìrà jínjìn,níbi tí kò sí ibi ìfẹsẹ̀lé.Mo ti wá sínú omi jínjìn;ìkún omi bò mí mólẹ̀.

Sáàmù 69

Sáàmù 69:1-7