Sáàmù 67:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kí Ọlọ́run kí ó ṣàánú fún wa kí o sì bùkún fún wakí ó sì jẹ́ kí ojú Rẹ̀ tàn yí wa ká,

2. kí ọ̀nà Rẹ̀ le di mímọ̀ ní ayé,ìgbàlà Rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè.

Sáàmù 67