Sáàmù 65:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyìn ń dúró dè ọ́, Ọlọ́run, ni Síónì;sì ọ ni a o mú ẹ̀jẹ́ wa ṣẹ.

Sáàmù 65

Sáàmù 65:1-10