Sáàmù 63:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Àwọn tí ó ń wá ọkàn mí ní a ó parun;wọn o sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìṣàlẹ̀ ilẹ̀ ayé.

10. Wọn ó ti ọwọ́ idà ṣubúwọn ó sì di jíjẹ fún kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀.

11. Ṣùgbọ́n ọba yóò yọ̀ nínú Ọlọ́runẹni tí o fi orúkọ Ọlọ́run búra yóò sògoṣùgbọ́n ẹnu àwọn òpùrọ́ la ó pa mọ́.

Sáàmù 63