Sáàmù 61:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Jẹ́ kí ẹ̀mí ọba kí o gùn,ọdùn Rẹ̀ fún ìrandíran.

7. Kí o máa jọba níwájú Ọlọ́run títí láé;pèsè àánú àti òtítọ́ Rẹ̀ tí yóò máa ṣe ìtọ́ju Rẹ.

8. Nígbà náà ni èmi ó máa kọrin ìyìn sí orúkọ Rẹ títí láékí ń san ẹ̀jẹ́ mí ní ojoojúmọ́.

Sáàmù 61