Sáàmù 60:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tèmi ni Gílíádì, tèmi sì ni Mánásè;Éfúráímù ni àsìbórì mi,Júdà sì ní ọ̀pá àṣẹ mi.

Sáàmù 60

Sáàmù 60:1-11