Sáàmù 60:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ gbà wá kí ó sì ràn wá lọ́wọ́,kí a lè gba àwọn tí o fẹ́ là.

Sáàmù 60

Sáàmù 60:3-9