Sáàmù 60:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ lórí àwọn ọ̀tá,nítorí asán ní ìrànlọ́wọ́ ènìyàn.

12. Nípa Ọlọ́run ni a ó ní ìṣẹ́gun,yóò sì tẹ̀ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.

Sáàmù 60