Sáàmù 6:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Ṣàánú fún mi, Olúwa, nítorí èmi ń ku lọ; Olúwa, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira.

3. Ọkàn mi wà nínú ìrora.Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa, yóò ti pẹ́ tó?

4. Yípadà, Olúwa, kí ó sì gbà mí;gbà mí là nípa ìfẹ́ Rẹ tí kì í ṣákìí.

Sáàmù 6