Sáàmù 6:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, Má ṣe bá mi wí nínú ìbínú Rẹkí ìwọ má ṣe nà mí nínú gbígbóná ìrunú Rẹ

2. Ṣàánú fún mi, Olúwa, nítorí èmi ń ku lọ; Olúwa, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira.

3. Ọkàn mi wà nínú ìrora.Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa, yóò ti pẹ́ tó?

Sáàmù 6