Sáàmù 58:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ̀yin ha ń sọ òdodo nítòotọ́ẹ̀yin ijọ ènìyàn?Ǹjẹ́ ẹ̀yìn ń ṣe ìdájọ́ tí ó ṣe títọ́ẹ̀yìn ọmọ ènìyàn?

2. Bẹ́ẹ̀ kọ́, nínú ọkàn yín ẹ̀yìn ń gbèrò àìsòdodo,Ọmọ yín sì tú ìwà ipá jáde ni ayé.

Sáàmù 58