Sáàmù 57:10-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Nítorí títóbi ní ìfẹ́ Rẹ, tí ó dé ọ̀run;òtítọ́ Rẹ tàn dé àwọ̀sánmọ̀.

11. Gbígbéga ni ọ, Ọlọ́run, ju àwọn ọ̀run lọ;kí ògo Rẹ̀ kí ó ju gbogbo ayé lọ.

Sáàmù 57