Sáàmù 56:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìwọ tí gbà mí lọ́wọ́ ikúàti ẹsẹ̀ mi lọ́wọ́ ìṣubú,kí èmí lè máa rìn níwájú Ọlọ́runní ìmọ́lẹ̀ àwọn alààyè.

Sáàmù 56

Sáàmù 56:4-13