Sáàmù 54:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gbà mí, Ọlọ́run nípa orúkọ Rẹ:dá mi láre nípa agbára Rẹ.

2. Gbọ́ àdúrà mi, Ọlọ́run;fi etí sí ọ̀rọ̀ ẹnu mi.

Sáàmù 54