Sáàmù 52:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èéṣé tí ìwọ fi ń ṣe féfé nínú ìwà ìkà,ìwọ alágbára ọkùnrin?Oore Ọlọ́run dúró pẹ́ títí

2. Ahọ́n Rẹ̀ ń gbìmọ̀ ìparun;ó dà bí abẹ mímú,ìwọ ẹni tí ń hùwà ìrẹ́jẹ.

Sáàmù 52