Sáàmù 51:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Nítorí ìwọ kò ní inú dídùn sí ẹbọ, tí èmi kò bá mú wá;Ìwọ kò ní inú dídùn sí ọọrẹ̀-ẹbọ sísun

17. Ẹbọ Ọlọ́run ni ìròbínújẹ́ ọkan ìròbìnújẹ́ àti ìrora àyà.

18. Ṣe rere ní dídùn inú Rẹ sí Síónì ṣe rere;tún odi Jérúsálẹ́mù mọ.

Sáàmù 51