Sáàmù 49:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ gbọ́ èyí, gbogbo ènìyàn!Ẹ fi etí sí i, gbogbo ẹ̀yin aráyé

2. Àti ẹni tí ó ga àti ẹni tí ó kérétalákà àti ọlọ́lá pẹ̀lú!

3. Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ọgbọ́nìsọ láti ọkàn mi yóò mú òye wá

4. Èmi yóò yí etí mi sí òweolókùn ni èmi yóò ṣi ọ̀rọ̀ ìkọ̀kọ̀ mí sílẹ̀ lójú okùn dùùrù.

Sáàmù 49