Sáàmù 49:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ gbọ́ èyí, gbogbo ènìyàn!Ẹ fi etí sí i, gbogbo ẹ̀yin aráyé

2. Àti ẹni tí ó ga àti ẹni tí ó kérétalákà àti ọlọ́lá pẹ̀lú!

3. Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ọgbọ́nìsọ láti ọkàn mi yóò mú òye wá

Sáàmù 49