Sáàmù 48:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Rìn Síónì kiri lọ yíká Rẹ̀,ka ilé ìsọ́ Rẹ̀

13. Kíyèsí odi Rẹ̀kíyèsí àwọn ààfin Rẹ̀kí ẹ̀yin lè máa wí fún ìran tí ń bọ̀

14. Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayéÒun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.

Sáàmù 48