Sáàmù 48:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹni ńlá ní Olúwa, tí o sì yẹ láti máa yìnní ìlú Ọlọ́run wa, lórí òkè mímọ́ Rẹ̀

2. Ó dára nínú ipò ìtẹ́ Rẹ̀ayọ̀ gbogbo ayéòkè Síónì, ní ìhà àríwání ìlú ọba ńlá.

3. Ọlọ́run wà nínú ààbò ààfin Rẹ̀;ó fi ara Rẹ̀ hàn láti jẹ́ odi alágbára.

Sáàmù 48