Sáàmù 42:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Bí àgbọ̀nrín tí ń mí hẹlẹ sí ìpa odò omi,bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mi n mì hẹlẹ sí ọ Ọlọ́run

2. Òùngbẹ Ọlọ́run ń gbẹ ọkàn mi, fún Ọlọ́run alààyè.Nígbà wo ni èmi ó lọ bá Ọlọ́run?

3. Oúnjẹ mi ní omijé miní ọ̀sán àti ní òru,nígbà tí àwọn ènìyàn ń wí fún mi ní gbogbo ọjọ́,“Ọlọ́run Rẹ̀ dà?”

Sáàmù 42