Sáàmù 38:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀,ìwọ Olúwa!Ọlọ́run miMá ṣe jìnnà sí mi

22. Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa,Olùgbàlà mi.

Sáàmù 38