Sáàmù 37:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dúró de Olúwa,kí o sì má a pa ọ̀nà Rẹ̀ mọ́,yóò sì gbé ọ lékèláti jogún ilẹ̀ náà:Nígbà tí a bágé àwọn ènìyàn búburú kúrò ìwọ yóò ri.

Sáàmù 37

Sáàmù 37:31-40