Sáàmù 37:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Má ṣe ìkanra nítorí àwọnolùṣe búburú,kí ìwọ má sì ṣe ṣe ìlàra nítorí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀;

2. nítorí pé wọn yóò gbẹbí koríko,wọn yóò sì Rẹ̀ dànùbí ewéko tútù

Sáàmù 37