Sáàmù 33:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ọkàn wa yọ̀ nínú Rẹ̀,nítorí pé, àwa gba orúkọ mímọ́ Rẹ̀ gbọ́

22. Kí àánú Rẹ, Olúwa, kí ó wà lára wa,àní gẹ́gẹ́ bí àwa ti ń ṣe ìrètí nínú Rẹ.

Sáàmù 33