Sáàmù 32:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Má ṣe dàbí ẹsin tàbí ìbaka,tí kò ní òyeẹnu ẹni tí a gbọdọ̀ fi ìjánu bọ̀,kí wọn má ba à sún mọ́ ọ.

10. Ọ̀pọ̀ ìkáàánú ní yóò wà fún ènìyàn búburú,ṣùgbọ́n ìfẹ́ Olúwa tí ó dúró ṣinṣinni yóò yí àwọn tí ó ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa ká.

11. Ẹ yọ̀ nínú Olúwa, kí ẹ sì ní inú dídùn, ẹ̀yìn olódodo;ẹ sì máa kọrin, gbogbo ẹ̀yìn tí àyà yín dúró ṣinṣin.

Sáàmù 32