Sáàmù 32:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìbùkún ni fún àwọntí a dárí ìrékọjá wọn jìn,tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.

2. Ìbùkún ni fún ọkùnrin náàẹni tí Ọlọ́run kò ka ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ̀ sí i lọ́rùnàti nínú ẹ̀mí ẹni tí kò sí ẹ̀tàn.

3. Nígbà tí mo dákẹ́,egungun mi di gbígbó dànùnípa ìkérora mi ní gbogbo ọjọ́.

Sáàmù 32