Sáàmù 28:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ Olúwa, mo képe àpáta mi;Má ṣe kọ eti dídi sí mi.Tí ìwọ bá dákẹ́ sí mi,èmí yóò dàbí àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun.

2. Gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi fún àánú,bí mo ṣe ń ké pé ọ́ fún ìràn lọ́wọ́,bí mo ṣe gbé àwọn ọwọ́ mi sókèsí ibi mímọ́ Rẹ jùlọ.

Sáàmù 28