Sáàmù 27:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa ni ìmọ́lẹ̀ mi àti ìgbàlà mi;ta ni èmi yóò bẹ̀rù? Olúwa ni ibi olódì ẹ̀mí mi,ta ni ẹni tí èmi yóò bẹ̀rù?

2. Nígbà tí àwọn ènìyàn búburú kọjú ìjà sí miláti jẹ ẹran ara mi,àní àwọn ọ̀ta mi àti àwọn abínúkú ù mi,wọn yóò kọsẹ̀, wọn yóò sì ṣubú.

3. Bí ọmọ ogun tilẹ̀ yí mi ká tí wọ́n sì dìde sí mi,ọkàn mi kì yóò bẹ̀rù;bí ogun tilẹ̀ dìde sí mi,nínú èyí ni ọkàn mi yóò le.

Sáàmù 27