Sáàmù 26:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣe ìdájọ́ mi, Olúwa,nítorí tí mo ti ń rìn nínú ìwà òtítọ́ ọ̀ mi,mo sì ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú OlúwaǸjẹ́ ẹsẹ̀ mi kì yóò yẹ̀.

2. Wádìí mi wò, Ìwọ Olúwa, kí o sì dán mi wò,dán àyà àti ọkàn mi wò;

3. Nítorí ìfẹ́ ẹ̀ Rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi,èmí sì ti rìn nínú òtítọ́ Rẹ.

Sáàmù 26