Sáàmù 25:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ẹni tí ó dúró tì ọ́;ojú kí yóò tìíàwọn tí ń ṣẹ̀ láìnídìíni kí ojú kí ó tì.

4. Fi ọ̀nà Rẹ hàn mí, Olúwa,kọ mi ní ipa tìrẹ;

5. ṣe amọ̀nà mi nínú ọ̀títọ́ ọ Rẹ, kí ò si kọ́ mi,Nítoríi ìwọ ni Ọlọ́run ìgbàlà mi;ìwọ ni mo dúró tì ní gbogbo ọjọ́.

Sáàmù 25