Sáàmù 25:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Wọn yóò lo ọjọ́ wọn nínú àlàáfíà,àwọn ọmọ wọn yóò sì gba ilẹ̀ náà.

14. Olúwa fi ọkàn tán, àwọn tí o bẹ̀rù u Rẹ̀;ó sọ májẹ̀mú Rẹ̀ di mímọ̀ fún wọn.

15. Ojú mi gbé sókè sọ́dọ̀ Olúwa,nítorí pé yóò yọ ẹsẹ̀ mi kúrò nínú àwọ̀n náà.

16. Yípadà sími, kí o sì ṣe oore fún mi;nítorí pé mo nìkàn wà, mo sì di olùpọ́njú.

Sáàmù 25