Sáàmù 25:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, ìwọ ni mo gbé ọkàn mi sókè sí.

2. Ọlọ́run, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ;Má ṣe jẹ́ kí ojú ó tì míMá ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀ta mi ó yọ̀ mí.

Sáàmù 25