8. Ọwọ́ Rẹ yóò wá gbogbo àwọn ọ̀ta a Rẹ rí;ọwọ́ ọ̀tún Rẹ yóò wà àwọn tí o kóríra Rẹ rí.
9. Nígbà tí ìwọ bá yọìwọ yóò mú wọn dàbí ìnà ìléru. Olúwa yóò gbé wọn mì nínú ìbínú Rẹ̀,àti pé iná Rẹ̀ yóò jó wọn run.
10. Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀,àti irú ọmọ wọn kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.