Sáàmù 21:12-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Nítorí pé ìwọ yóò mú wọn yí ẹ̀yìn wọn padànígbà tí o bá pinnu láti ta wọ́n ní ọfà.

13. Gbígbéga ni ọ Olúwa, nínú agbára Rẹ;a ó kọrin, a ó yín agbára a Rẹ̀.

Sáàmù 21