Sáàmù 15:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, Ta ni yóò máa gbé nínú àgọ́ mímọ́ Rẹ?Ta ni yóò máa gbé ní òkè mímọ́ Rẹ?

2. Ẹni tí ń rìn déédéétí ó sì ń sọ òtítọ́,láti inú ọkàn Rẹ̀

3. tí kò fi ahọ́n Rẹ̀ sọ̀rọ̀ ẹni lẹ́yìn,tí kò ṣe ibi sí aládùúgbò Rẹ̀tí kò sì sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí ẹnìkejì Rẹ̀,

Sáàmù 15