Sáàmù 148:11-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Àwọn ọba ayé àti ènìyàn áye gbogboàwọn ọmọ aládé àti gbogbo àwọn onídájọ́ ayé,

12. Ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrinàwọn arúgbó àti àwọn ọmọdé.

13. Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ Olúwanítorí orúkọ Rẹ̀ nìkan ni ó ní ọláògo Rẹ̀ kọjá ayé àti ọ̀run

14. Ó sì gbé ìwo kan sókè fún àwọn ènìyàn Rẹ̀,ìyìn fún gbogbo ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ àní fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,àwọn ènìyàn tí ó súnmọ́ ọ̀dọ̀ Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Sáàmù 148