Sáàmù 147:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ ọ̀rọ̀ Rẹ̀ di mímọ̀ fún Jákọ́bùàwọn òfin àti ìlànà Rẹ̀ fún Ísírẹ́lì

Sáàmù 147

Sáàmù 147:17-20