8. Olúwa mú àwọn afọ́jú ríran Olúwa, gbé àwọn tí a Rẹ̀ sílẹ̀ ga Olúwa fẹ́ràn àwọn olódodo.
9. Olúwa ń dá ààbò bo àwọn àlejòó sì ń dá àwọn aláìní baba àti opó síṣùgbọ́n ó ba ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú jẹ́.
10. Olúwa jọba títí láéỌlọ́run Rẹ, ìwọ Síónì, àtifún gbogbo ìran, Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.