Sáàmù 145:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi yóò gbé ọ ga, Ọlọ́run ọba mi;Èmi yóò yin orúkọ Rẹ̀ láé àti láéláé

2. Ní ojoojúmọ́ èmi yóò yìn ọ́èmi yóò sì pòkìkí orúkọ Rẹ láé àti láéláé.

Sáàmù 145