Sáàmù 144:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbàmí kí ó sì yọ mí nínú ewukúrò lọ́wọ́ àwọn ọmọ àjèjìtí ẹnu wọn kún fún èké,tí ọwọ́ ọ̀tún wọn jẹ́ ọwọ́ ọ̀tún èké.

Sáàmù 144

Sáàmù 144:1-15