Sáàmù 143:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Olúwa,nítorí èmi fí ara mi pamọ́ sínú Rẹ̀.

Sáàmù 143

Sáàmù 143:1-12