Sáàmù 142:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Wo ọwọ́ ọ̀tún mi kí ó sì wò ókò sí ẹni tí ó ṣe àníyàn fún mièmi kò ní ààbò;kòsí ẹni tí ó ṣe àníyàn fún ayé mi.

5. Èmi kígbe sí ọ, Olúwa:èmi wí pe, “ìwọ ni ààbò mi,ìpín mi ní ilẹ̀ alààyè”

6. Fi etí sí igbe mi, nítorí tí èmiwà nínú àníìrètígbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi,nítorí wọ́n lágbára jù mi lọ

7. Mú mi jáde kúrò nínú túbú,kí èmi lè máa yin orúkọ Rẹ.Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò péjọ nípa minítorí iwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ba mi ṣe.

Sáàmù 142