Sáàmù 14:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Asiwèrè wí nínú ọkàn Rẹ̀ pé,“kò sí Ọlọ́run.”Wọ́n díbàjẹ́, iṣẹ́ wọn sì burú;kò sí ẹnìkan tí ó ṣe rere.

2. Olúwa sì bojú wolẹ̀ láti ọ̀run wálórí àwọn ọmọ ènìyànbóyá ó le rí ẹni tí òye yé,ẹnikẹ́ni tó ń wá Ọlọ́run.

Sáàmù 14