Sáàmù 138:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa tilẹ̀ ga, ṣíbẹ̀ ó júbà àwọn onírẹ̀lẹ̀;ṣùgbọ́n agbéraga ní ó mọ̀ ní òkèrè réré.

Sáàmù 138

Sáàmù 138:1-8